Jòhánù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù sì jẹ́rìí nípa rẹ̀, ó kígbe, ó sì wí pé, “Èyí ni ẹni tí mo sọ̀rọ̀ rẹ̀ pé, ‘Ẹni tí ń bọ̀ lẹ́yìn mi pọ̀ jù mí lọ, nítorí òun ti wà ṣáájú mi.’ ”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:5-21