Jóẹ́lì 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ẹ̀yín tí mú fàdákà mi àti wúrà mi, ẹ̀yin si tí mú ohun rere daradara mi lọ sínú tẹ́ḿpìlì yín.

Jóẹ́lì 3

Jóẹ́lì 3:1-9