Wọn yóò sáré bi àwọn alágbára;wọn yóò gùn odi bí ọkùnrin ológun;olúkúlúkù wọn yóò sì rìn lọ ní ọ̀nà rẹ̀,wọn kì yóò sì yà kúrò ni ọ̀nà wọn.