Jóẹ́lì 2:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin yóò ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti jẹ, titi ẹyin yóò fi yóẹ ó sì yín orúkọ Olúwa Ọlọ́run yín,ẹni tí ó fi ìyanu bá yín lò;ojú kì yóò sì ti àwọn ènìyàn mi láéláé.

Jóẹ́lì 2

Jóẹ́lì 2:16-28