Jóẹ́lì 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má bẹ̀rù, ẹranko igbó,nítorí pápá-oko ihà ń rú,nítorí igi ń so èso rẹ̀, igi ọ̀pọ̀tọ́àti àjàrà ń so èso ipá wọn.

Jóẹ́lì 2

Jóẹ́lì 2:12-23