Jóẹ́lì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Njẹ́ nítorí náà nísínsin yìí,” ni Olúwa wí,“Ẹ fi gbogbo ọkàn yín yípadà sí mi,àti pẹ̀lú ààwẹ̀, àti pẹ̀lú ẹkún, àti pẹ̀lú ọ̀fọ̀.”

Jóẹ́lì 2

Jóẹ́lì 2:11-21