Ayé yóò mì níwájú wọn;àwọn ọ̀run yóò wárìrì;òòrùn àti òṣùpá yóò ṣókùnkùn,àwọn ìràwọ̀ yóò sì fà ìmọ́lẹ̀ wọn ṣẹ́yìn.