Jóẹ́lì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbọ́ èyí ẹ̀yin àgbààgbà;ẹ fi etí sílẹ̀ gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ará ilẹ̀ náà.Ǹjẹ́ irú èyí ha wà ní ọjọ́ yín,tàbí ní ọjọ́ àwọn baba yín?

Jóẹ́lì 1

Jóẹ́lì 1:1-8