Jóẹ́lì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, sí ọ ni èmi o ké pè,nítorí iná tí run pápa oko tútú ihà,ọwọ́ iná sí ti jó gbogbo igi igbó.

Jóẹ́lì 1

Jóẹ́lì 1:12-20