Jóẹ́lì 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ojú kí ó tì yín, ẹ̀yin àgbẹ̀;ẹ pohùn réré ẹkún ẹ̀yin olùtọ́jú àjàrà,nítorí àlìkámà àti nítorí ọkà báálì;nítorí ìkórè oko ṣègbé.

Jóẹ́lì 1

Jóẹ́lì 1:2-20