Jeremáyà 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ahọ́n wọn dàbí ọfà olóróó ń sọ ẹ̀tàn; oníkálukú sì ńfi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ àlàáfíà síaládúgbò rẹ̀; ní inúọkàn rẹ̀, ó dẹ tàkúté sílẹ̀.

Jeremáyà 9

Jeremáyà 9:1-15