Jeremáyà 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dípò èyí, wọ́n ti tẹ̀lé agídí ọkàn wọn, wọ́n ti tẹ̀lé Báálì gẹ́gẹ́ bí àwọn baba wọn ṣe kọ́ wọn.

Jeremáyà 9

Jeremáyà 9:13-23