Jeremáyà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n tọ́jú ọgbẹ́ àwọn ènìyàn mi gẹ́gẹ́bí èyí tí kò jinlẹ̀.“Àlàáfíà, àlàáfíà,” ni wọ́n ń wí,nígbà tí kò sí àlàáfíà.

Jeremáyà 8

Jeremáyà 8:1-15