Jeremáyà 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìgbà tí àwọn baba ńlá yín ti jáde ní Éjíbítì títí di òní, ni èmi ti ń rán àwọn ìránṣẹ́ mi, àwọn wòlíì sí yín.

Jeremáyà 7

Jeremáyà 7:15-29