Jeremáyà 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èyí ni Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ ogun wí: Tẹ̀ṣíwájú kí ẹ kó ẹbọ sísun yín àti àwọn ẹbọ yóòkù papọ̀ kí ẹ̀yin kí ó sì jẹ ẹran wọ́n fúnra yín.

Jeremáyà 7

Jeremáyà 7:16-25