Jeremáyà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ilé yìí, tí a fi orúkọ mi pè ti di ihò àwọn ọlọ́sà lọ́dọ̀ yín ni? Èmi ti ń wò ó! ni Olúwa wí.

Jeremáyà 7

Jeremáyà 7:5-18