Jeremáyà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùṣọ́ àgùntàn pẹ̀lú agbo wọn yóò gbógun tì wọ́n.Wọn yóò pa àgọ́ yí wọn ká,olúkúlùkù yóò máa jẹ ní ilé rẹ̀.”

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:1-12