Jeremáyà 6:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ gbé asọ ọ̀fọ̀wọ̀, kí ẹ sì sùn nínú eérú, ẹsọ̀fọ̀ pẹ̀lú ìpohùnréré ẹkúngẹ́gẹ́ bí i lórí ọmọkùnrin yín, kanṣoṣonítorí pé lójijì ni àwọn apanirun yóò kọlù wá.

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:18-28