Jeremáyà 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì dìmọ́ra pẹ̀lú ọrun àti ọ̀kọ̀,Wọ́n jẹ́ ẹni ibi, wọn kò sì ní àánúwọ́n ń hó bí omi òkun, bí wọ́nti ṣe ń gun àwọn ẹsin wọn lọ;wọ́n sì wá bí ọkùnrin tí yóòjà ọ́ lógun, ìwọ ọmọbìnrin Síónì.”

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:18-29