Jeremáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kún fún ìbínú Olúwa, èmi kò sì le è pa á mọ́ra.“Tú u sí orí àwọn ọmọ ńigboro, àtisórí àwọn ọmọkùnrin tí wọn kórawọn jọ pọ̀, àti ọkọ àti aya ni a òmú sínú rẹ̀, àti àwọn arúgbótí ó ní ọjọ́ kíkún lórí.

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:3-18