Jeremáyà 52:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹ́sàn án, oṣù mẹ́rin ìyàn ìlú náà sì ti burú dé ibi pé kò sí oúnjẹ kankan mọ́ fún àwọn ènìyàn láti jẹ.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:1-12