Jeremáyà 52:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń sọ̀rọ̀ rere sí i, ó sì fún un ní ìjókòó ìgbéga, èyí tí ó ju ti àwọn Ọba yóòkù lọ tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní Bábílónì.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:26-34