Jeremáyà 52:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Ríbílà ni ilẹ̀ Hámátì Ọba náà sì pa wọ́n. Báyìí ni Júdà sì sá kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:23-31