Jeremáyà 52:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pomegiranátì mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún ni ó wà ní àwọn ẹ̀gbẹ́ rẹ̀. Àpapọ̀ gbogbo pomegiranátì sì jẹ́ ọgọ́rùn ún kan.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:13-27