Jeremáyà 52:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nebusarádánì balógun ìsọ kó gbogbo àwọn tálákà àti gbogbo àwọn tí ó kù ní ìlú náà lọ sí ilẹ̀ àjèjì pẹ̀lú àwọn oníṣọ̀nà tí ó kù àti gbogbo àwọn tí ó ti lọ sọ́dọ̀ Ọba Bábílónì.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:8-21