Jeremáyà 52:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáná sun pẹpẹ Olúwa, ààfin àti gbogbo àwọn ilé Jérúsálẹ́mù. Ó sì dáná sun gbogbo àwọn ilé ńláńlá.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:7-16