Jeremáyà 52:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Ríbílà ni Ọba Bábílónì ti pa ọmọkùnrin Sedekáyà lójú rẹ̀; ó sì tún pa gbogbo àwọn aláṣẹ Júdà.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:1-11