Jeremáyà 51:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sá kúrò ní Bábílónì! Sá àsálàfún ẹ̀mí rẹ! Má ṣe ṣègbé torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.Àsìkò àti gbẹ̀san Ọlọ́run ni èyí,yóò sán fún òun gẹ́gẹ́ bí ó ti tọ́.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:3-8