Jeremáyà 50:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn tí ó rí wọn, ti pa wọ́n jẹàwọn ọ̀ta wọ́n sì wí pé, ‘Àwa kò jẹ̀binítorí pé wọ́n ti sẹ̀ sí Olúwa ibùgbéòdodo àti ìrètí àwọn baba wọn.’

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:5-10