Jeremáyà 50:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó máa bèèrè ọ̀nà Síhónì, oju wọnyóò sì yí síhà ibẹ̀, wí pé ẹ wá, ẹ jẹ́ kí adarapọ̀ mọ́ Olúwa ní májẹ̀mú ayé-rayé,tí a kì yóò gbàgbé.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:2-14