Jeremáyà 50:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí i kìnnìún tí ń bú láti igbó Jọ́dánì.N ó lé Bábílónì kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀ ní kánmọ́ kánmọ́.Ta ni ẹni àyànfẹ́ náà tí n ó yàn?Ta ló dàbí mi, ta ló dàbí mi,ta ló sì le dojú ìjà kọmí?”

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:35-46