Jeremáyà 50:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wò ó! Ọ̀wọ́ ọmọ ogun láti ìhà àríwá;orílẹ̀ èdè ńlá àti àwọn Ọba pípọ̀ ni à ńgbé dìde láti òpin ilẹ̀ ayé.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:37-46