Jeremáyà 50:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Idà lórí àwọn wòlíì èkéwọn yóò di òmùgọ̀! Idà lórí àwọn jagunjagun,wọn yóò sì kún fún ẹ̀rù.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:26-39