Jeremáyà 50:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wò ó, èmi lòdì sí àwọn onígbéraga,”ni Olúwa Ọlọ́run,“ọmọ ogun wí, nítorí ọjọ́ rẹti dé tí ìwọ yóò jìyà.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:23-34