Jeremáyà 50:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìlú ní apá àríwá yóòsì máa gbógun tì wọ́n.Gbogbo àwọn ènìyàn àti ẹranko ni yóòsá kúrò ní ìlú yìí.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:1-6