Jeremáyà 50:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́tí sí àwọn tí ó sálọ tí ó sì sálà láti Bábílónì,sì sọ ní Síónì, bí Olúwa Ọlọ́run wa ti gbẹ̀san,ẹ̀san fún tẹ́ḿpílì rẹ̀.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:26-33