Jeremáyà 50:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo dẹ pàkúté sílẹ̀fún ọ ìwọ Bábílónì,kí o sì tó mọ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀,o ti kó sínú rẹ̀. A mú ọ nítorí pé o tako Olúwa.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:20-34