Jeremáyà 50:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú kúrò ní Bábílónì olùgbìnàti olùkórè pẹ̀lú ohun ìkórè rẹ̀.Nítorí idà àwọn aninilárajẹ́ kí oníkálùkù padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀,kí oníkálukú sì sá padà sí ilẹ̀ rẹ̀.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:7-25