Jeremáyà 50:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Dúró sí àyè rẹ ìwọ Bábílónìàti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ ta ọfà náà.Ẹ ta ọfà náà síi, nítorí ó ti sẹ̀ sí Olúwa.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:9-15