Jeremáyà 50:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú yóò ti ìyá rẹ, ẹni tí ó bí ọyóò sì gba ìtìjú.Òun ni yóò jẹ́ kékeré jù nínú àwọn orílẹ̀ èdè,ilẹ̀ aṣálẹ̀ àti ihà tí kò lọ́ràá.

Jeremáyà 50

Jeremáyà 50:6-17