Wọn yóò jẹ ìkórè rẹ àti oúnjẹ rẹ,àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti obìnrin,wọn yóò sì jẹ agbo àti ẹran rẹ,wọn yóò jẹ àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ.Pẹ̀lú idà ni wọn ó runìlú tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé.”