Jeremáyà 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ti pa irọ́ mọ́ Olúwa;wọ́n wí pé, “Òun kì yóò ṣe ohun kan!Ibi kan kì yóò sì tọ̀ wá wá;àwa kì yóò sì rí idà tàbí ìyàn.

Jeremáyà 5

Jeremáyà 5:8-22