Jeremáyà 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ sí ọgbà àjàrà rẹ̀, kí ẹ sì pa wọ́n run,ẹ má ṣe pa wọ́n run pátapáta.Ya ẹ̀ka rẹ̀ kúrò,nítorí àwọn ènìyàn wọ̀nyí kì í ṣe ti Olúwa.

Jeremáyà 5

Jeremáyà 5:9-15