Jeremáyà 49:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ló dé tí ẹ fi ń fi àfonífojì yín yangàn?Ẹ fi àfonífojì yín yangàn pẹ̀lú èṣo rere,ẹ̀yin ọmọbìnrin aláìsòótọ́.Gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ yín, ẹ sì wí pé,‘ta ni yóò kò mí lójú?’

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:1-6