Jeremáyà 49:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi fi ara mi búra ni Olúwa wí, wí pé, “Bósírà yóò bayé ara rẹ̀ jẹ́. Yóò di ẹni ẹ̀gàn, ẹni èpè àti ẹni ẹgún, àti gbogbo ìlú rẹ̀ yóò di ìbàjẹ́ títí láé.”

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:8-22