Jeremáyà 48:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gòkè lọ sí Lúhítì,wọ́n ń sunkún kíkorò bí wọ́n ti ń lọ;ní ojú ọ̀nà sí Horonáímùigbe ìrora ìparun ni à ń gbọ́ lọ.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:1-6