Jeremáyà 48:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo orí mi ni ó pá,gbogbo irungbọ̀n ni a gé kúrò,gbogbo ọwọ́ ni a ṣá lọ́gbẹ́, àtiaṣọ ọ̀fọ̀ ní gbogbo ẹ̀gbẹ́.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:29-45