Nítorí náà, mo pohùnréréẹkún lórí Móábù fún àwọnará Móábù ni mo kígbe lóhùn raraMo kẹ́dùn fún àwọn ọkùnrin Kíháráṣè.