Jeremáyà 48:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kúrò ní àwọn ìlú rẹ, kí o sì máa gbé láàrin àwọn òkúta,ẹ̀yin tí ó ti ń gbé inú ìlú Móábù.Ẹ dàbí i àdàbà tí ó kọ́ ìtẹ́ rẹ̀sí ẹnu ihò.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:21-30