Jeremáyà 48:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Móábù kò ní ní ìyìn mọ́,ní Héṣíbónì ni wọn ó pète ìparun rẹ̀,‘Wá, kí a pa orílẹ̀ èdè náà run.’Àti ẹ̀yin òmùgọ̀ ọkùnrin pàápàá ni a ó pa lẹ́nu mọ́,a ó fi idà lé e yín.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:1-3